Ẹ̀ pade wa lórí TikTok Live fún ìpàdé tó ṣe pàtàkì nípa ìdí tí ọjà títà rẹ̀ fi ń falẹ̀ àti bí ìmọ̀ data ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mú kóyà.
Bí o bá jẹ́ oníṣòwò, alákóso oja, tàbí ẹni tó nífẹ̀ẹ́ sí ìmọ̀ data, pade olóòtú Theophilus Adegbohungbe àti onímọ̀ nípa dàtà Oluwatosin Babalola bi won yóò se ma fún ọ ní àwọn ìmọ̀ràn tó wúlò tó o lè lo lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.

